Take a fresh look at your lifestyle.

Ìpínlẹ̀ Abia: Àìtètèdé ọkọ ṣe ìdíwọ́ fún ètò pínpín ìwé ìdìbò.

0 286

Àwọn Àjọ Èléto Ìdìbò (INEC) ní Isi Alangwa ẹkùn Àríwá Ìjọba Ìpínlẹ̀ Abia sọ wí pé àwọn ni ìṣòro pínpín ìwé ètò ìdìbò, èyí ni o fa ti idiwọ rán pẹ fí wá.

 

Àwọn Àjọ̀ Èléto Ìdìbò de Ibùdó ìbò ni déédéé aago mẹ́wá àbọ̀ ni ẹkùn Àríwá àti gúúsù Umuahia, Aba àti Isi Alangwa.

 

Ọ̀gbẹ́ni “Emmanuel Ukaegbu, òṣìṣẹ́ elétò Ìdìbò ni o jẹ kó di mímọ̀ wí pé ọkọ̀ wọn to pẹ́ dé ni ó fà ìjákulẹ̀ yìí, ṣùgbọ́n ètò ìdìbò ti ń lọ lọ́wọ́lọ́wọ́ ní ìrọwọ-ìrọsẹ.

 

Lákòótán, àwọn Oludibo ti wa lori ìlà, wọ́n sì ti gbáradi lati dìbò ní Abúlé Umuaro ní Isi Alangwa.

 

Olubunmi Adeyẹmọ.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button