Alága tí Àjọ tó ń bójú tó àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè lágbáyé (Nigerians in Diaspora Commission NiDCOM), Abike Dabiri-Erewa, tí pé gbogbo àwọn olúkópa nínú ìdánilẹ́kọ̀ọ́ Àjọ Yúrópù àtí Àjọ Arínrìn àjò Àgbáyé (European Union and International Organisation for Migration IOM), látí ló ẹ̀kọ́ tí wọ́n kọ́ níbí ìdánilẹ́kọ̀ọ́ náà fún àwùjọ.
Ó pépé èyí níbí ìparí ayẹyẹ ìdánilẹ́kọ̀ọ́ tí ẹ̀kọ́ rẹ̀ dá lórí Ìṣàkóso ètò ìrìn àjò èyí tí á fí sàmì láti ọdún 2020-2022, ní Abùjá, Olú-ìlú Nàìjíríà.
Dabiri-Erewa sọ pé;
“Oun àdáyébá ní ìrìn àjò tí á kò lé dá dúró. Sibẹsibẹ, ìrìn àjò àìtọ́ ní á gbọ́dọ̀ bú ẹ̀nu àtẹ lú àti pé gbogbo wà lá niṣẹ́ látí ṣé. Ààrẹ Muhammadu Buhari tí dá àwọn ọmọ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tó jù ẹgbẹ̀rún mẹ́wàá lọ́ 10,000 pàdà látí Orílẹ̀-èdè Libiya àtí àwọn orílẹ̀-èdè mìíràn lágbáyé.”
“IOM tí gbìyànjú lọ̀pọ̀lọpọ̀ lórí ọ̀rọ̀ yíì, sibẹ ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ọmọ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ṣì wà káàkiri àgbáyé tí wọ́n ń kígbe fún ìrànlọ́wọ́. Ẹ́ Jẹ́ kí á só ọ̀wọ́ pọ̀ láti dènà ìrìn àjò àìtọ́ yìí pẹ̀lú lílò àwọn ẹ̀kọ́ wọnyí, kí á sí máa gbà àwọn ènìyàn àwùjọ wà ní iyaju.” O fí kún.
Tún kà nípa: IWD 2023: DC, UN, UNDP Ṣé Ìsàmì Ayẹyẹ Àwọn Obìrin Nàìjíríà Pẹ̀lú Àmì-Ẹrí
Aṣojú European Union, Eleni Zerzelidou gbóríyìn fún Alága NiDCOM fún iṣẹ́ takuntakun pẹ̀lú ìdánilẹ́kọ̀ọ́ fún àwọn aráàlú, ọ sí rọ̀ ìgbìmọ̀ náà látí kópa nínú ẹ̀kà tí Fintech àtí Integration, lafikun pé ìgbìmọ̀ náà ní òun àgbàrá lọ́wọ́.
Ìdánilẹ́kọ̀ọ́ náà jẹ́ tí Àjọ Yúrópù àtí Àjọ arínrìn àjò Àgbáyé EU-IOM fún Ìdáàbòbò àtí ibarẹnigbepọ àwọn atínrín àjò àgbáyé.
Lekan Orenuga
Leave a Reply