Take a fresh look at your lifestyle.

Àjọ Àgbáyé (UN) Yóò Pín $250m Fún Àwọn Orílẹ̀-èdè Ní Áfíríkà

0 303

Akọ̀wé Àgbà tí Àjọ Àgbáyé António Guterres tí kéde ìpín owó tó tóbi jùlọ́ ní ilẹ̀ Áfíríkà fún ìṣẹ́ pajawiri.
Ó ń sọ̀rọ̀ lẹ́gbẹ̀ẹ́ kàn níbí ìpàdé AU ní olú ìlú orílẹ̀-èdè Ethiopia, Addis Ababa.

Ọ̀gbẹ́ni Guterres sọ pé $250m yóò ná lórí òun tó ṣé àpèjúwe bí “àwọn rògbòdìyàn gbàgbé làgbáyé” pẹ̀lú iyán ní Áfíríkà.

Èyí lè dùn bí owó púpọ ṣùgbọ́n ní ìbẹrẹ oṣù yìí àjọ UN sọ pé òún nilo $2.6bn kàn látí ṣé ìrànlọ́wọ́ fún Orílẹ̀-èdè Somalia èyí tí ọ̀dá àtí ọ̀gbẹ́lẹ̀ tó burú jùlọ́ ń dà láàmú látí bí ogójì ọdún sẹyìn.

Tún kà nípa: IWD 2023: DC, UN, UNDP Ṣé Ìsàmì Ayẹyẹ Àwọn Obìrin Nàìjíríà Pẹ̀lú Àmì-Ẹrí

Ọ̀wán oúnjẹ ní ilẹ̀ Áfíríkà ní ọkàn pàtàkì lórí òún tí ìpàdé náà dá lé lórí.

Nínú àwọn mìíràn ní ìṣòwò jakejado ní ilẹ̀ Áfíríkà àtí rògbòdìyàn káàkiri nílẹ̀ Áfíríkà. Èyí tó farahàn pé kó lè sí àṣeyọrí láìpẹ́ lórí àwọn ọran wọnyí.

Lekan Orenuga

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button