Take a fresh look at your lifestyle.

Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà Ṣé Àtìlẹ́yìn Fún Àwọn Ọ́lọ́tẹ̀ Nínú Rògbòdìyàn Tó Ṣẹ̀lẹ̀ Ní Tigray

0 268

Ààrẹ Eritrea Isaias Afwerki tí fí ẹsùn kán Orílẹ̀-èdè America fún àtìlẹ́yìn tí wọ́n ṣé fún àwọn ọ́lọ́tẹ̀ tí Tigray làkókò ogún àbẹ̀lé tó parí láìpẹ́ yíì ní àríwá Ethiopia.

Ààrẹ Afwerki ń sọrọ làkókò ifọrọwanilẹnuwo pẹ̀lú àwọn òníròyìn níbí tí o tí sọ pé àdéhùn àláfíà tó wáyé láàrín Ethiopia àti Tigray People’s Liberation Front (TPLF) ní America yàrá tí síwájú làkókò tí wọ́n tí rí pé àwọn ọ́lọ́tẹ̀ tí ń pàdánù ogún náà.

Tún kà nípa: Àwọn Òṣìṣẹ́ Ìrànlọ́wọ́ Tó Ní Idẹna Láti Kúrò Ní Tigray Ethiopia Tí Gbà Òmìnìra

Nínú ifọrọwanilẹnuwo náà, ó tún jẹwọ fún ìgbà àkọ́kọ́ pé àwọn ọgọ-ọgọrùn ènìyàn ló kú nínù rògbòdìyàn náà, bótílẹ̀jẹ̀ pé kó ṣé àlàyé lórí àwọn olufaragba Ìlú Eritrea.

Ẹgbẹ́ ọmọ ogún Eritrea ṣé àtìlẹ́yìn fún àwọn ọmọ ogún Etiopia làkókò ogún pẹ̀lú TPLF àtí pé Orílẹ̀-èdè America ati awọn ẹgbẹ ẹtọ fí ẹsùn kàn Eritrea lórí àwọn ìwà ìká tó burú jù tí wọ́n wù nínú rògbòdìyàn náà.

Lekan Orenuga

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button