Take a fresh look at your lifestyle.

Àwọn Adóòlà Ẹ̀mí Fi Iṣẹ́ Wọn Tì Sí Ẹ̀gbẹ́ kan Ní Orílẹ̀-èdè Syria Àti Turkey

0 284

 

Àwọn adóòlà ẹ̀mi fi iṣẹ́ wiwa ènìyàn tó nù tàbí tí ó kú wọn tì sí ẹ̀gbẹ́ kan ní Orilẹ-èdè Syria àti Turkey látàrí ilẹ̀ rírì tó ṣẹlẹ̀ ní àwọn Orílẹ̀-èdè náà.

Àwọn ènìyàn tó ti kú báyìí ti ju Ẹgbẹ̀rún mẹ́ẹdọ́gbọ̀n lọ. Wíwá ènìyàn tó nù tàbí tó ti kú kiri ti wá dópin gẹ́gẹ́ bí ìròyìn se sọ ní ọjọ́ ẹtì.

Lẹ́yìn tí àwọn àjọ adóòlà ẹ̀mí wá kiri títí fún wákàtí méjìdínláàdọ̀fà, àwọn àjọ náà wà gbàgbọ́ pé kò sí ènìyàn kankan tó há sí abẹ́ ilẹ̀ tó tún wà láàyè mọ́ .

 

Tèmítọ́pẹ́ Òbísẹ̀san

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button