Take a fresh look at your lifestyle.

Tinubu/ Shettima yóò ṣe àpèjọ ààrẹ ní Kwara, ní ọjọ́ Ìṣẹ́gun

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

0 279

Ìgbìmọ̀ ìpolongo ààrẹ fún ẹgbẹ́ All Progressives Congress (APC),ti fọwọ́sí ìpolongo ààrẹ Tinubu/ Shettima, tí yóò wáyé ní ọ̀la,ọjọ́ Ìṣẹ́gun,ọjọ́ kẹtàdín-lógún,ní Ìlrin, olú-ìlú Kwara,ilà oòrùn àringbùngbùn Nàìjíríà.

Ìgbìmọ̀ ìpolongo ààrẹ nínú àtẹ̀jáde kan tí alága,ìgbìmọ̀ ìbílẹ̀ elétò ìbáraẹnisọ̀rọ̀, (LOC), Alhaji Saadu Salahu, sọ pé wọn tí buwọ́lu àpèjọ náà,èyí tí yóò wáyé ní agogo mẹ́wàá òwúrọ̀.

Gẹ́gẹ́ bí àtẹ̀jáde náà ṣe sọ,ìròyìn sọ pé gbogbo ẹgbẹ́ APC tó pọ̀ jù àti àwọn olólùfẹẹ́ wọn jákèjádò orílẹ̀-èdè ló ti gúnlẹ̀ sí ìlú Ìlọrin,olú ìlú.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button