Take a fresh look at your lifestyle.

Ìjọba Nàìjíríà Bẹnu Àtẹ́ Lu Àkọlù Sí Ibùdó Ọkọ̀ Ojú Irin

0 579

Ìjọba àpapọ̀ ti korò ojú sí jíjí àwọn èrò ọkọ̀ ojú irin gbé ní ibùdókọ̀ Tom Ikimi, Igueben, ní ìpínlẹ̀ Edo.

 

Ẹka ìgbòkègbodò ọkọ̀ ìjọba àpapọ̀ fi àrídájú hàn pé ìjọba tí n gbìnyànjú láti gba àwọn tí wọ́n jígbé padà. Àtipé àwọn Ọlọ́pàá ti bẹ̀rẹ̀ sí ní lépa àwọn ọ̀daràn náà, ààbò tí ó péye sì wà fún àwọn èrò tí ó kù.

 

A kò ì tíì le sọ pàtó iye ènìyàn tí ó wà nínú ìgbèkùn àwọn ajínigbé náà.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button