Owó Pọun Egypt já wá lẹ̀ sí dọla Améríkà ní 25.90 ní Ọjọ́bọ̀, èyí tó pọ̀jù láàárín ọjọ́ kàn látí ìgbà tí ilé ifowopamọ àpapọ̀ ìlú Egypt jù ọwọ́ sílẹ̀ níyè 14.5% ní ọjọ́ kẹtadinlọgbọn, Oṣù Kẹwàá, ọdún tó kọjá.
International Monetary Fund IMF, tí ṣé ìlérí irọrun owó bílíọ̀nù Mẹ́tà dọla látí gbà àwọn orílẹ̀-èdè là lórí ètò òwò, láàrín oṣù Mẹ́rin dín làádọ́ta (46), ní oṣù kẹwàá
Orílẹ̀-èdè Egypt tí ń ṣé ètò ẹ̀yàwó látí Oṣù kẹta tí ògún tí bẹ́ sílẹ̀ ní Ukraine tó ṣé òkùnfà àìtó owó ilẹ̀ òkèèrè, tó sí fà ailọ déédé ọjà òkèèrè àti ilọju pọ̀ àwọn ètò èbúté ọkọ ojú omi.
Owó náà tí ń dínkù láti 19.7 sí dọla látí Oṣù Kẹta ọdún tó kọjá.
Lekan Orenuga
Leave a Reply