Take a fresh look at your lifestyle.

Owó Epo Rọ̀bì Subú Lulẹ̀ Yakata Látàrí Àìrajaja Ọrọ̀ Ajé Lágbàyéé

0 398

Owó orí epo ròbì já, látàrí àìsí oníbàárà ní ọjà àgbáyé. eléyìí wáyé ní ọjọ́ kẹrin osù kíní (4th January, 2023).

 

Ìsubú náà tún wáyé látàrí àfojúsùn àìrajaja ọrọ̀ ajé ní orílẹ̀ èdè  Amẹrika àti àrùn covid-19 tí ó ń bá orílẹ̀ èdè China fínra.

 

Nígbà tí ìrètí sì wà tẹ́lẹ̀ pé, owó orí epo rọ̀bì yóò lọ sí ààdọ́fá dọ́là ($110) ní ọdún 2023.

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button