Take a fresh look at your lifestyle.

Ìròyìn Tuntun Lórí Ògún Ukraine Àti Russia

0 224

Ni ọjọ Ẹtì àwọn aláṣẹ ìjọba ilẹ̀ Ukraine jabọ pé Russia kọlù Ukraine pẹ̀lú àwọn òún Ìjà Ògún “drones Shahed” mẹrindinlogun ti Iran ní gbogbo alẹ̀. Èyí jẹ́ ọjọ́ Kejì lẹyìn tí Ìlú Moscow rán dosinni Ado-Oloro látí bá àwọn òún amayedẹrun tó ṣé pàtàkì.

IBARAẸNISỌRỌ LÁÀRÍN RUSSIA ÀTI CHINA

Ààrẹ Russia Vladimir Putin sọ pé òún fẹ́ kí ìfọwọ́sowọ́pọ̀ àwọn jinlẹ̀ sí lórí iṣẹ́ ológun pẹ̀lú ilẹ̀ China, O sí gbèrò láti gbà Ààrẹ China Xi Jinping lalejo ní Russia ní ìgbà òjò tí ọdún 2023. Ààrẹ Jinping sọ fún Putin nínú ijiroro wọ́n pé “ọna sí àwọn ijiroro àlàfíà lórí Ukraine kìí yóò wà ní irọrun, àtí pé China yóò tẹ̀síwájú látí ṣé àtìlẹ́yìn rẹ̀ àti ìdúró òdodo lórí ọran náà.” Akọroyin Orílẹ̀-èdè China sọ lẹyìn ìpàdé wọ́n lórí fanran.

ÀTÌLẸ́YÌN NATO

Akọ̀wé Gbogbogbò ti NATO Jens Stoltenberg pé àwọn orílẹ̀-èdè ọmọ ẹgbẹ́ NATO ń látí pèsè àwọn òhun ìjà fún Ukraine, ní ìbámu sí ifọrọwanilẹnuwo kàn. Ààrẹ Ukarain Volodymyr Zelensky sọ pé àwọn àṣẹ afẹ́fẹ́ ní agbede-meji, gúsù, ila-oorun, àtí ìwọ̀-oòrùn Ukraine tí kọ̀ àwọn misaili mérin lé làádọ́ta 54 Russia àti àwọn drones Mọkanla ni Ọjọ́bọ̀. Ṣùgbọ́n ilé ìgbé méjì dín lógún àti àwọn ẹrọ amayedẹrun tó ṣé pàtàkì mẹwàá míràn ní wọ́n tí parun ní Ọjọ́bọ̀.

IKỌLÙ ỌJỌ́BỌ̀

Ilé-iṣẹ́ Ààbò tí Russia ní ọjọ́ Ẹtì ṣàpèjúwe ikọlù náà bí òún tó lágbára lórí èpò Ukraine, àwọn òún amayedẹrun àtí ilé iṣẹ́ ológun nípa lílò àwọn òún Ado olóró. Kremlin sọ pé ọ ṣé ní láànù pé òún ìjà ọkò òfurufú ti Ukraine kan tí wọ́n já nínú afẹ́fẹ́ tí Belarus ní Ọjọ́bọ̀. Ilé-iṣẹ́ ààbò tí Ukraine sọ pé òún yóó ṣé ìwádìí ìṣẹlẹ̀ náà, ní iyànjú pé o jẹ́ inúnibíni Russia àti pé òún ní ẹtọ látí dáàbòbo àwọn ojú ọ̀run rẹ̀.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button