Take a fresh look at your lifestyle.

Rihanna Fi Fán-án-rán Fídíò Ọmọbíbí Inú Rẹ̀ Léde

0 292

Olùgba àmìẹ̀yẹ Rihanna ti fi fán-án-rán àwòrán rẹ̀ kan léde àti ti ọmọdékùnrin rẹ̀, lẹ́yìn tí ọmọ náà pé osù méje.

 

Àwọn olólùfẹ́ rẹ̀ bá a dáwọ̀ọ́ ìdùnnú nígbà tí wọ́n rí fídíò rẹ̀ pẹ̀lú ọmọbíbí inú rẹ̀ ní ọjọ́ kẹtàdínlógún, osù kejìlá ọdún 2022 (December 17, 2022).

 

Rihanna bí ọmọ rẹ ní ọjọ́ kẹtàlá, osù kaàrún, léyìí tí ó sì se àpèjúwe ọmọ náà gẹ́gẹ́ bíi ọmọ olóríirejùlọ, àtipé ọmọ ìdùnnú ni.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button