Take a fresh look at your lifestyle.

Uganda Fí Ẹsùn Kàn Tọkọtaya Ọmọ Amẹ́ríkà Kan Lórí Fífi Ìyà Jẹ̀ Ọmọdé

0 260

Àwọn Ọlọ́pàá Uganda sọ pé tọkọtaya ará Amẹ́ríkà kan tí wọ́n fí ẹ̀sùn kàn án ní Uganda pẹ̀lú “ìjìyà gbígbóná janjan” tí ọmọkùnrin ọmọ ọdún mẹ́wàá tí wọ́n ti gbà ṣọmọ.

Àwọn ọmọ ọgbọ̀n ọdún lé méjì, ní wọ́n fí ẹ̀sùn kàn ní ọjọ́ Ẹtì tí wọ́n sì mú wọ́n lọ́ sí Ẹ̀wọn Luzira, ilé-ẹ̀wọ̀n ààbò gíga kàn tí Olú-ìlú Kampala.

Gẹ́gẹ́ bíí ẹ̀sùn náà, tọkọtaya náà “máa ń fí ìyà jẹ̀ ọmọdé kunrin náà ní igbagbogbo.” Ọmọ náà wà ní ilé àwọn ọmọ tó ní Ìpenija àrà láàrín ọdún 2020 àtí 2022.

Àwọn aladugbo ló fí tó àwọn agbofinro létí.

Làkókò àbẹwò àwọn ọlọ́pàá sí ilé náà, wọ́n ríi nínú àwòrán CCTV tó fí hàn pé ododo ní ọrọ naa.

Ọmọkùnrin náà jẹ́ ọkàn nínú àwọn ọmọ mẹ́tà tí tọkọtaya náà gbà tọ. Wọ́n jẹ̀ ọkàn nínú àwọn tó yọnda àrà wọ́n látí ṣé iṣẹ ìlú ní Jinja ní Uganda ní ọdún 2017 kí wọ́n tó lọ tẹ̀dó sí Naguru, àgbègbè nlá kán ní Kampala.

Ìjọba AMẸ́RÍKÀ tí pàṣẹ ijẹni-nìyá ní ọdún 2020 lòdì sí isọdọmọ àwọn ọmọdé ọmọ Ugandan tí kìí ṣé alaini-baba pẹ̀lú àwọn ìdílé ní Amẹ́ríkà.

Lekan Orenuga

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button