Take a fresh look at your lifestyle.

Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà kọ́ Àwọn Tó Nílò Ìrànlọ́wọ́ Lẹ́kọ̀ọ́ Kí Wọ́n Tó Jáde Níbi Ìpàgọ́

0 237

Ọgọ́rùn ún ènìyàn káàkiri orílẹ̀-èdè yìí ni wọn ti gba ẹ̀bùn irinṣẹ́ ìrónilágbára lọ́wọ́ ìjọba orílè-èdè Nàìjíríà.

Komisọ́na Ìjọba àpapọ tí orílè-èdè yìí fún àwọn àtìpó àti ogun léndé, Imaan Suleiman-Ibrahim ló pín àwọn ẹ̀bùn wọ̀nyìí fún wọn.

 

Àwọn ènìyàn náà “Persons of Concern” ni àwọn àtìpó, ogun-lendé, àwọn tí wọ́n dá padà láti ibi kan tàbí orílẹ̀-èdè ede kan ṣí òmíràn abbl.

 

Ó sọ wípé, àjọ náà ti jí gìrì sí ọ̀pọ̀lọpọ̀ ètò láti ri wípé ayé àwọn ènìyàn wọ̀nyi dára.

 

 

Tèmítọ́pẹ́ Òbísẹ̀san

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button