Ààrẹ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Muhammadu Buhari ń ṣe àkóso lórí ìpàdé orí ẹrọ pẹlú Ìgbimọ Aláṣẹ ti ijọba, ti o waye ni ilé Igbimọ ti ilé ààrẹ, Abuja.

Igbákejì Ààrẹ, Ọjọgbọn Yemi Osinbajo, Olóyè àwọn Oṣiṣẹ fún Ààrẹ, Ọjọgbọn Ibrahim Gambari àti Olórí àwọn òṣìṣẹ́ ilé ìjọba, Dọ́kítà Folashade Yemi-Esan wa lára àwọn ti o wa si ìpàdé náà.

Àwọn mìíràn ni àwọn mínísítà fún Àlàyé, Lai Mohammed, Ìṣowó, ìṣúná àti ètò orílẹ̀-èdè, Zainab Ahmed àti Adájọ́, Abubakar Malami, pẹ̀lú àwọn mìíràn.
Ọláyinká Akíntọ́lá.
Leave a Reply