Take a fresh look at your lifestyle.

Ààrẹ China Àtí Ààrẹ France Ṣé Ìpàdé Lórí Ogún Russia Àtí Ukraine

0 383

Ààrẹ China Xi Jinping àti Ààrẹ Faranse Emmanuel Macron tí tún fí ipá wọ́n hàn lórí lílòdi sí òun ìjà apanirun nínú ogún ní Ukraine, Ààrẹ Faranse sọ ní ìbámu sí àwọn ìròyìn tó ń já kalẹ.

Àwọn Ààrẹ méjèèjì náà tó ṣé ìpàdé idakọnkọ kàn ní ọjọ́ Ìṣẹgun, tún jíròrò lórí àwọn ọ̀rọ̀ bíi ìpèsè ‘atilẹyin owo’ sí àwọn ọ̀rọ̀-àjé tó ṣẹ̀ṣẹ̀ ń dàgbàsókè èyí tó tọ́kasí orílẹ̀-èdè Zambia.

Orílẹ̀-èdè China ní o yà orílẹ̀-èdè Zambia jùlọ lágbáyé, ti orílẹ̀-èdè Faransé jẹ́ amugba lẹgbẹ wọ́n.

Ilé-iṣẹ́ ìròyìn tí ìlú China Xinhua tún sọ pé Xi bí sé sọ pé China àti Faranse yóò ṣé itẹsiwaju lórí ìdàgbàsókè ibaṣepọ wọ́n.

Lekan Orenuga

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button