Olùpẹ̀tù sí aláwọ̀ ECOWAS ti parí ibẹ̀wò rẹ sí Orílè-èdè Burkina Faso latari iditegbajoba to sele ni ojo eti to koja, ekeji re laarin osu mejo
Mahamadou Issoufou se ìpàdé pẹlu olórí tuntun, Captain Ibrahim Traoré.
Nígbàtí o ba awon oniroyin sọrọ leyin Ipade, Olupetu sí aawọ ECOWAS náà fi dá awon omo orile-ede Burkina Faso pé gboingboin ni ajo náà wá léyìn wọn bi ike pàápàá jù lakoko to fe nira díẹ yii. O sọ pé àwọn yóò ròyin ìdí wíwá wọn fún ààrẹ ti ECOWAS lọ́wọ́lọ́wọ́ àti àwọn olórí orílẹ̀-èdè
Ní àkókò ìpàdé, olórí tuntun orílè èdè Burkina Faso se Ìlérí pé òun yóò mú ìlérí tí adarí tẹ́lẹ̀ ṣe ní oṣù keje sẹ nípa ṣíṣe ọ̀tun ìbò àti dídá ìjọba padà fún ìjọba alágbádá ó pẹ́ tán oṣù keje ọdún 2024.
Tèmítọ́pẹ́ Òbísẹ̀san
Leave a Reply