Olórí Afipágbàjọba àti Afipáperarẹ̀- ládarí, Ibrahim Traore se ìpàdé pẹ̀lú àwọn òṣìṣẹ́ rẹ̀ ní ọjọ́ Àìkú lẹ́yìn ìditẹ̀gbàjoba ológun.
Olórí aditẹ̀gbajoba tẹ́lẹ̀ Lieutenant-Colonel Paul-Henri Sandaogo Damiba náà Kọ̀wé fipò sílẹ léyìn ìsọ̀rọ̀pọ̀ pẹ̀lú olórí tuntun.
Kí ó tó di wípé ìṣẹ̀lẹ̀ náà sẹlẹ̀ lọ́jó ẹtì tó kọjá, ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn ló péjọ ṣí Olú ìlú orílè-èdè náà, Ouagadougou tí wọ́n fẹ́ kí ọ̀gbéni Damiba máa lọ pé àwọn kò fẹ ìjọba rẹ mọ́.
Èyí jẹ́ ìgbà èkejì tí irú rògbòdìyàn ìgbàjọba bẹ́ẹ̀ máa ṣẹlẹ̀.
Ìdá ogójì ọmọ orílè-èdè Burkina Faso ni kòsí lábẹ́ ìṣèjọba orile-èdè náà.
Tèmítọ́pẹ́ Òbísẹ̀san
Leave a Reply