Take a fresh look at your lifestyle.

Lílò Ipò Mi Láti Jẹkí Nàìjíríà Túbá Túṣẹ́

0 280
Ààrẹ Muhammadu Buhari sọ pé ohùn tí ló ọdún méje lórí ìtẹ̀ làti jẹ́ kí Orílẹ-èdè Nàìjíríà yọrí sí réré, èyí sì ṣeé ṣe pẹlu iranlọwọ Ọlọ́run àti ẹni kọọkan wà. 

 

Ọrọ yii wáyé níbí èéto Ọrọ Àkànsọ Ààrẹ lórí ẹ̀rọ ayélujára làti sàmì ayẹyẹ Àjọ̀dún Kéjìlélọ́gọ́ta Òmìnira Orílẹ-èdè Nàìjíríà.

 

O sọ pé:  “A yàn mí láti sìn Orílẹ-èdè yí ati Àwọn Olùṣíṣepọ pẹ̀lú mí, mo sì rí gẹ́gẹ́ bíi àǹfààní láti sọ Nàìjíríà dì Orílẹ-èdè tí Ó dára, tí ó sì ṣeé ṣe fún wa pẹ̀lú Ìfọwọsowọpọ wà, Ọlọ́run Alágbára àti Àtilẹyin ẹni kọọkàn wá jẹkí àwọn àlá ipilẹ réré yii wá sí ìmúṣẹ.”

 

Ààrẹ ló àǹfààní yìí láti dúpẹ́ gidigidi lọwọ wà,  pẹ̀lú ìwúrí àti imọníyàn yín, fún oriyín yin láti sìn Orílẹ-èdè yii bí ó ti tọ àti bí ó ti yẹ.

 

Pẹ̀lú ọkàn imoore sì Ọlọ́run, mo ń dupẹ gidigidi lọ́wọ́ wà tí ẹ fún mi ní Oore-Ọfẹ làti dárí Orílẹ-èdè yii nígbà tí ó nira pupọ.

 

Buhari ni, Orílẹ-èdè yìí ni Ìdojúkọ tí ó pọ, ṣùgbọ́n Ọlọ́run fún wọ́n ní àǹfààní láti ṣàkítiyan àti pínnù làti ṣe àṣeyọrí.

 

Láàrín ọdún diẹ sẹ́yìn a dójú kọọ ìṣòro àìmọye tí ó le dá Orílẹ-èdè wá ru ṣùgbọ́n Ọlọ́run fún wá ní Oore-Ọfẹ làti Ṣe àṣeyọrí.  Ẹ̀mí iranlọwọ aláìlẹ́gbẹ ọmọ Nàìjíríà kọọkan ní ó fún wa ní ìdánilójú Olúborí.”
Nínú Ẹ̀mí Iṣọkan yìí  ni mo gbà wá níyànjú gẹgẹ bii ẹnì kọ̀ọ̀kan ati lapapọ làti fi mọ sọ́kàn làti ṣíṣe lórí àwọn ìṣòro tí ó ń jẹyọ, ” Láfikún.

 

Aladari Orílẹ-èdè yii ló àǹfààní Ọrọ Òmìnira Ori Afẹ́fẹ́ tí ó jẹ àṣekágbá tí yóò fi gbé ìjọba silẹ lọdun to n bọ̀  làti rọọ  àwọn ọmọ ìlú làti béèrè ẹ̀tọ́ wọ́n lọwọ àwọn Oṣiṣẹ Ìjọba.

 

Àtúnṣe ní ibí ìṣẹ ijọba tí ń so èso réré, pápá jùlọ nínú èéto ìjìṣẹ.  Látàrí èyí, mo rọọ ẹnì kọ̀ọ̀kan wá láti béèrè Gbùngbùn ẹ̀tọ́ wá lọwọ àwọn Aladari tí ó kàn,” gẹ́gẹ́ bí ó ti sọ.

 

Lórí èéto Ilẹ Okere, Àwọn Aladari Nàìjíríà ṣe ìpinnu pé Orílẹ-èdè wá yóò tẹ̀síwájú làti ló àǹfààní àjọṣe pò àti ìbàdọ̀rẹ́ tí ó nipọn láwùjọ àwọn Orílẹ-èdè  làti fọwọ wẹ ọwọ  pelu ibaṣèpọ to dán mọran-in làti jeki atijẹ́ àti atimú ọmọ Orilẹ-ede kọọkan gbe peeli sii.

 

 

Olubunmi Adeyẹmọ.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button