Take a fresh look at your lifestyle.

Èéto Iléṣẹwọ́gbẹ: Ẹbùn Bílíọ̀nù Méjì Lè Nírìnwò Ẹgbẹ̀rún Dọ̀là Fún Àjọ̀dún Ìpolongo Ará Ìlú Jákèjádò Àgbàye

0 368
Ẹgbẹ tí a mọ sí Ará-Ìlú Àgbàye tí polongo ẹ̀bùn Bílíọ̀nù méjì lè nírìnwò Ẹgbẹ̀rún Dọ̀là fún Àjọ̀dún 2022 lórí Ìpolongo Ará Ìlú Jákèjádò Àgbàye láti fòpin sí iṣẹ to kọjá àlá lásìkò yí.

 

Ìpolongo Ọlọ́sẹ mẹ́fà yí wá sí ìdánú dúró pẹ̀lú Àjọ̀dún wákàtí mẹsan ní ipele méjì, bẹ̀rẹ̀ ni Igun Black Star ni Accra, Ghana, Harith ló ṣe èéto yí nígbàtí ó parí sì Ìlú New York pẹ̀lú ìdánilẹ̀kọ́ láti ẹnu Citi àti Cisco.

Lópin Ìpolongo yìí, Ẹgbẹ tí a mọ sí Ará-Ìlú Àgbàye ní àwọn Olórí làgbáyé, àwọn ilé ìṣẹ ńláńlá ati Àwọn Olúdàsilẹ̀ Ẹgbẹ Olúránlọwọ láti fi òpin sí iṣẹ tí ó kọjá àlá ní kíákíá kí wọ́n sì ná Ẹgbẹ̀rún mẹ́ta miliọnu Dọ̀là lórí ọjọ́ iwájú àwọn Obìnrin; kí wọ́n dẹkùn Bílíọ̀nù mẹ́wá ọdọọdún lórí ìyípadà ọjọ́; kí wọ́n náà Ẹẹdẹgbẹ̀tá miliọnu Dọ̀là láti fi rán àwọn Agbẹ lọ́wọ́ láti dojú kọ ọ̀wọ́n góogó oúnjẹ làgbáyé; kí IMF ní wàrà ń ṣe sáá tú wá lára lórí gbése to ń rún ọ̀rọ̀ ajé wà.  Bí ó ti lẹ jẹ́ pé àbájáde Ìpolongo àti ifara-ẹniji dúró fún Ìdàgbàsókè Ìdojúkọ, iṣẹ àti àìní tí ń kojú ènìyàn ní gbogbo àgbáyé, ìṣẹ pọ gidi láti ṣe ṣáájú ìpàdé G20 àti COP27 ni Oṣù Kọkànlá.

 

Olubunmi Adeyẹmọ.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button