Take a fresh look at your lifestyle.

Ọkọ́ Tuntun Mẹ́wà Fún àwọn Ọlọ́pàá Ìpínlè Óyo.

0 261

Gómìnà ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́,Seyi Makinde fi ọkọ̀ tuntun mewa tá àwọn ọlọ́pàá ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ lọrẹ fún ìtèsíwájú ètò àbò tó péye.

Gómìnà Makinde ṣe èyí nínú ìfọ̀rọ̀wérọ̀ to wáyé ni ilé iṣé ìjọba tó wà ní Agodi ni Ibadan.

Nínú òrò ìdúpé rẹ, kọmísọ̀nà àwọn Ọlọ́pàá ni ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́,CP Adebowale William, dùpẹ̀ púpò lówó Gómìnà fún ìrànlọ́wọ́ rẹ,ti àwọn Ọlọpa Ìpínlè náà ti jáfàní àti pi pèsè àwọn ohun ètò ààbò lórísirísi.

O tẹnu mọ wípé, ọ̀nà tí ogbó àti ọpọlọ ti Ìpínlè náà ló ṣe ìrànlọ́wọ́ láti di ìwà ìbàjẹ́ kú.
O bẹrẹ fún ìrànlọ́wọ́ àkòtun láti ọwọ́ ìjọba ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ fún ìtèsíwájú to jù bà yìí ló

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button