Ohun tó wù yín, ni kí ẹ wí, ètò ìdìbò ọdún 2023 yóò wáyé ní Nàíjíríà – Lai Mohammed
Minisita fun eto iroyin ati asa lorilẹ ede Naijiria,Lai Mohammed ti ni ki awọn ọmọ orilẹ ede Naijiria ati ilẹ̀ agbaye fọkan balẹ pe eto idibo ọdun 2023 lorilẹ ede Naijiria yoo lọ ní irọwọ ati irọsẹ.
Minisita sóró yii lasiko to n ba awón akóroyin sóró léyin ipade igbimó alasé to waye nile aaré to wa niluu Abuja.Minisita tésiwaju pe , iró ati ahesó óró patapata gbaa ni awón kan n só pe eto iddibo ódun 2023 yoo mu wahala ati idiwó dani nitori awón ipenija to n dojuko orilé ede yii nipa eto aabo.
.Lai Mohammed wa gbosuba fun awón ẹ̀sọ́ alaabo fun gudu gudu meje , yaya mẹfa lati mojuto eto aaboo ati alaafia lorilẹ ede Naijiria.
Leave a Reply