Ààrẹ Cyril Ramaphosa ti ṣe ìtẹ́wọ́gbà àdéhún ùn Ààrẹ Ìgbìmọ̀ aláwọ̀ funfun (EU), Charles Michel nípa ṣíṣe àtìlẹyìn àwọn akitiyan Áfíríkà láti le pèsè oúnjẹ tótó tí ó sì tún ṣẹ́kù.
Adehun naa yoo tun ṣe iranlọwọ lati din bi Adulawọ ṣe darade gbigba awọn ohun ọgbin okeere wọle lati ibomiiran ni agbaye.
Aarẹ Ramaphosa gbalejo aarẹ Michel ni ibugbe ọfiisi rẹ ni Mahlambandlopfu ni ọjọ Iṣẹgun.
Leave a Reply