Take a fresh look at your lifestyle.

Ààrẹ Mùhámmádù Bùhárí gúnlẹ̀ sí Lísíbọ̀nì, Pọ́túgàlì.

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

0 230

Ààrẹ Mùhámmádù Bùhárí ti gúnlẹ̀ sí Lísíbọ̀nì,lórílẹ̀-èdè Pọ́túgàlì fún àbẹ̀wò.

Awọn alaṣẹ orilẹ-ede Pọtugali ati diẹ ninu awọn ọmọ Naijiria  ti n gbe nibẹ  ni wọn wa ki kaabọ ni papakọ ofurufu Lisibọni.

Ibẹwo naa, ti yoo bẹrẹ ni Ọjọru,ọjọ kọkandin-lọgbọn, Oṣu Kẹfa, yoo fun Naijiria ati Pọtugali ni aye lati finukonu ati fọwọ si awọn adehun ni awọn ẹka loriṣiriṣi.

Aarẹ Pọtugi, Marcelo Rebelo de Sou ni o pe aarẹ Buhari fun abẹwo naa.

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button