Ààrẹ Mùhámmádù Bùhárí ń darí àpèjọ ọlọ́sẹ̀ẹ̀sẹ̀ Ìgbìmọ̀ Aláṣẹ àpapọ̀ lọ́wọ́lọ́wọ́ ní gbàngàn ìgb̀imọ̀, Víllà,olú-ìlú, Àbújá.
Awọn ti o wa nibi ipade naa ni; Igbakeji Aarẹ Yẹmi Ọṣinbajo; Akọwe fun ijọba apapọ, Boss Mustapha, Olori awọn oṣiṣẹ lapapọ, Dokita Fọlaṣade Yẹmi-Ẹsan ati Olori awọn Oṣiṣẹ Aarẹ, Ọjọgbọn Ibrahim Gambari.

Awọn minisita to tun wa nibẹ pẹlu wọn ni; Adajọ agba ati Minisita fun eto idajọ, Abubakar Malami, Minisita ibaraẹnisọrọ ati Aṣa, Lai Mohammed, Ofurufu, Hadi Sirika,Eto ọgbin, Mohammed Mahmood, ti iṣẹ ati Ibugbe, Babatunde Fashọla.

Awọn miiran tun ni; Minisita Ayika, Mohammed Abdullahi, ti Ipinlẹ fun Olu-ilu, Ramatu Tijjani,Minisita ipinlẹ fun Ayika, Sharon Ikeazor ati Minisita ti Ipinlẹ fun eto ọgbin, Mustapha Shehuri.

Olori awọn oṣiṣẹ ati awọn minisita toku n kopa lati awọn ọfiisi wọn ni Abuja.
Alaye ni kikun nigbamii……..
Leave a Reply