Ẹgbẹ́ Àtìlẹ́yìn iṣé-ọnà ilé-ìfowópamọ́ Àgbáyé ṣàbẹ̀wò sí ìpínlẹ̀ Bọ̀rọ̀nú
Eyitayọ Fauziat Oyetunji
Àwọn ọmọ ẹgbẹ́ alátìlẹyìn iṣẹ́-ọnà ilé-ìfowópamọ́ àgbáyé tí ọ̀gá àjọ iṣẹ́ lórí Multi Sectoral Crisis Recovery Project (MCRP) Serena Cavicchi,ṣadarí rẹ̀, ti ṣàbẹwò sí Ìpínlẹ̀ Bọ̀rọ̀nú lórí iṣẹ́ ọnà, mímójútó díẹ̀ nínú àwọn iṣẹ́ àkànṣe àti gbégbí iṣẹ́ ikọ̀ àwọn MCRP ní ìpínlẹ̀ náà lárugẹ.

Awọn ọmọ ẹgbẹ Atilẹyin iṣẹ ọna miran to tun wa nibẹ ni : oludamọran si ile-ifowopamọ Agbaye lori Ise akanṣe MCRP, Ọgbẹni Masroor Ahmed, Chidozie AG, Onimọ-ọrọ-aje ati eto ọgbin, Anas Abba Kyari, Aṣoju Iṣowo Agba, Ọjọgbọn Ahmed Chinade, Aabo Ayika ati Nkem Uzochukun C1 ati alamọja C3.

Lẹyin ipade pataki pẹlu ijọba ipinlẹ Bọrọnu ni awon osise MCRP tun ṣabẹwo si ibudo isaba mayedẹrun ni Maiduguri, ẹgbẹ Alakoso Agba ni ipinlẹ Bọrọnu MCRP, Baba Zanna Abdulkarim, ṣe abewo si okan lara awon ile ise ilera marundin-lọgbọn ti ikọ naa kọ ni agbegbe Abujan talakawa, nibi ti Oṣiṣẹ alabojuto ile-iwosan, Yachilla Waziri,ti sọ pe lẹhin kikọ Ile-iṣẹ ilera akọkọ naa, iṣẹ akanṣe naa tun pese ẹrọ amunawa alagbara oorun fun ile-iwosan ọhun,kanga igbalode ati awọn oogun to ṣe pataki,


Leave a Reply