Take a fresh look at your lifestyle.

Ààrẹ Mùhámmádù Bùhárí ń darí àpéjọ ìgbìmọ̀ aláṣẹ

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

0 208

Ààre Mùhámmádù Bùhárí ń darí ìpàdé ọlọ́sẹ̀ẹ̀sẹ̀ Ìgbìmọ̀ Aláṣẹ àpapọ̀ lọ́wọ́lọ́wọ́ ní ilé-iṣẹ́ Ààrẹ, Víllà ,ní ìlú Àbújà.

Awọn ti o wa nijoko nibi ipade ti o bẹrẹ ni deede agogo mẹsan owurọ, ni Igbakeji Aarẹ Yẹmi Ọsinbajo; Akọwe fun ijọba apapọ, Boss Mustapha,Ọga agba fun awọn oṣiṣẹ lapapọ, Dokita Fọlaṣade Yẹmi-Ẹsan ati Ọga agba fun awọn Oṣiṣẹ  Aarẹ, Ọjọgbọn Ibrahim Gambari.

Awọn minisita to tun wa nijoko ni; the adajọ gbogbogboo ati Minisita fun Idajọ Abubakar Malami,alaye ati aṣa, Lai Mohammed,alumọni omi, Suleiman Adamu, Sayẹnsi ati amayedẹrun Ogbonnaya Onu, ọrọ agbofinro, Muhammad Dingyadi,ọrọ irilẹ-ede, Rauf Aregbesola and idagbasoke idaraya ati Ọdọ, Sunday Dare.

Awọn miiran ni Minisita  Ipinlẹ fun alumọni inu ilẹ ati Idagbasoke Irin, Uche Ogar, Minisita ipinlẹ fun Agbara, Jedy Agba, ati alabaṣiṣẹpọ rẹ, iṣẹ ati Ibugbe, Mu’azu Sambo.

Awọn ọmọ ẹgbẹ  miiran n kopa lati awọn ọfiisi wọn ni Abuja.

Awọn alaye nigbamii……..

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button