Take a fresh look at your lifestyle.

Bá òkú ìṣe ò tán

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

0 454

Àwọn ọmọdé tí ó ní ààrùn jejerẹ ní Sudan tí ń gbé ní ilé ńlá kan tí a npè ní “Ìrétí wà nínú wa” ní olú-ìlú Khartoum, kò sọ̀rètí nù fún ọjọ́ iwájú.

Wọ́n wá láti oríṣiríṣi ìlú ní orílẹ̀-èdè naa ni Ìlà Oòrùn Áfíríkà, wọn sì dúpẹ́ lọ́wọ́ àtìlẹ́yìn ẹgbẹ́ “A Ṣe Gbogbo Wà” ti o gbe bukaata oúnjẹ àti ìtọ́jú wọn.

Yasir Ali,ọmọ ọdun mẹwa kan jẹ akọkọ lati agbegbe North Darfur,awọn ẹbi rẹ kuro ni ilu Fashir lẹhin ti o bẹrẹ si ni maa jẹ irora ninu ara rẹ, nigbati wọn de Khartoum wọn dari wọn si ile nla naa.

Lakoko Ramadan, Ile-iṣẹ Ifowosowopo ati Iṣọkan orilẹ-ede Tọki (TIKA) ṣeto  iftar ti wọn si n pese ounjẹ fun ogoji  ọmọde  ti o ni aarun jẹjẹrẹ  ti wọn wa ninu ile nla naa.

Ikan lara awọn ọmọ naa, Muhammed Ibrahim  ti  bẹrẹ chemotherapy ati pelu aisan rẹ; ó ní òun fẹ́ di awakọ̀ òfuurufú nígbà tí òun bá dàgbà tí ohun yoo sì mọlu  káàkiri.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button