Ààrẹ Muhammadu Buhari ti fi ìmoore Nàìjíríà hàn sí Akọ̀wé Agba tẹlẹri fun United Nations, Ban Ki-Moon fún ìfaraji rẹ̀ sí ìlọsíwájú àti ìdàgbàsókè ètò ọrọ̀ ajé orílẹ̀-èdè náà.
Aarẹ ti o ba Ban Ki-Moon sọrọ lori ẹrọ ibaraẹnisọrọ ni ọsan Ọjọ Aje fi muilẹ wipẹ ọwọ ti oun ni fun ko kere rara.
Ban Ki-Moon gbóríyìn fún Ààrẹ fún bó ṣe ń bójú tó ààbò àti àwọn ìṣòro tó ń dojú kọ orílẹ̀-èdè náà.
Leave a Reply