Take a fresh look at your lifestyle.

Ọ̀jọ̀gbọ́n Osibajo Kí Asíwájú Bola Tinubu Fún Ayẹyẹ Ọjọ́ Ìbí Rẹ̀

0 273

Igbákejì Ààrẹ Yemi Osinbajo ti kí Gómìnà Ìpínlẹ̀ Èkó nígbàkanrí àti  olórí ẹgbẹ́ òsèlú All Progressives Congress, Asiwaju Bola Tinubu, kú oríire ayẹyẹ ọjọ́ ìbí rè pẹ̀lú bí ó ṣe pé aadorin ọdun (70th)

Ọjọgbọn Osinbajo pẹlu gbogbo ẹbi, awọn ọrẹ ati alabaṣiṣẹpọ lo yọ pẹlu rẹ wọn si gbadura fun pe ki Ọlọrun fun ni okun, ọgbọn ati ojurere si.

Igbakeji Aarẹ yìn iṣẹ ribiribi ti Gomina tẹlẹri ti gbe se si orilẹ-ede Naijiria ni awọn ẹka lọkan-o-jọkan.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button