Take a fresh look at your lifestyle.

Ìkọlù Ọkọ̀ Ojú-Irin: Ìjọba Ti Kó Àwọn tó farapa Lọ Sí Ilé Ìwọ̀sàn

0 236

Wọ́n ti ko  àwọn èrò arinrinajo  inú ọkọ̀ ojú-irin tó farapa  ní Kaduna láti Abuja ní òwúrọ̀ yìí. Àwọn òṣìṣẹ́ ààbò, àwọn òṣìṣẹ́ ilé-iṣẹ́ tí ó ń ṣe ìtọ́jú pàjáwìrì ní ìpínlẹ̀ Kaduna (SEMA) àti àwọn ọmọ ẹgbẹ́ Red Cross Nàìjíríà ni ó sisẹ́ náà.

 Àwọn arìnrìn-àjò tí ó farapa ni a ti gbé lọ sí àwọn ilé-ìwòsàn.

A le ranti pe, oko oju irin ti o n lọ si Kaduna lati Abuja ti o ko awọn arinrin ajo to to ojì-din-lẹwá d́in ńi ẹgbẹ́rún (970) ni wọn kọlu ni ọjọ Aje, lẹba ọna Rijana-Katere ni ipinlẹ Kaduna.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button