Ilé-iṣẹ́ tó ń mójútó àjàkálẹ̀ ààrùn lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà, (NCDC) ti ṣàlàyé lórí bó ṣe ń lọ pé àwọn ènìyàn mẹ́tàdínlógún míràn tún ti kó ààrùn còrónà jákèjádò orílẹ̀-èdè.
Awọn eniyan wọnyii si jẹyọ ni ipinlẹ marun:Ipinlẹ Imo -mẹjọ,Ọyọ -mẹrin,Olu-ilu -meji,Ọṣun -meji,Kano -ẹyọkan.
Lọwọlọwọ bayii,awọn eniyan ẹ̀ẹ́dẹ́gbàta- le- ni -ọ̀kẹ́ -méjìlá- abo -o -din- ni ẹ̀ta- le- loojì lo ti ko aarun ọhun, ẹ̀ẹ́dẹ́gbàrún- le -ni- ọ̀kẹ́- méjìlá- o -le- ni ọ̀kan- din- nigba eniyan ti gba iwosan, ti èjì-le-ni-ojì- le- ni- ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ́ẹ̀rìndínlógún eniyan si ti jepe oluwa.
Leave a Reply