Take a fresh look at your lifestyle.

Mo ti se ojúṣe mi fún Nàíjíríà-Buhari

0 424

Aarẹ Muhammadu Buhari ti ni oun ti ṣe ojuse  fun orilẹ ede Naijria , o wa ku ki awọn  ọmọ orilẹ ede Naijiria mọ rírí isẹ́ ti oun se.

Aarẹ Buhari sọrọ yii lasiko eto ifọrọwanilẹnuwo ti o se pẹlu ile-isẹ mohun-maworan NTA to waye lọjọBọ.

o ni ; ”Mo fẹ lọ sinmi lẹyin ti mo ba fi aleefa silẹ ni osu mẹtadinlogun to ku bayii..”, “Mo ti jẹ gomina ati minisita  tẹlẹri, ni bayii mo tun ti jẹ aarẹ orilẹ ede Naijria,Nitorinaa gbogbo ipele to wa labẹ oselu ni mo ti gba kọja, kin ni ohun to tun dara julọ ti mo tun lee se fun orilẹ ede Naijiria?

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button