Take a fresh look at your lifestyle.

ACF gbóríyìn fún Olúbádàn tí ó papò dà

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

0 347

Oloye Audu Ogbeh, Alaga ACF lorilẹ-ede, sọ ninu ọrọ kan pe “Ọba tii ṣe ẹni ọwọ jepe oluwa  ni ọjọ Aiku, ọjọ keji, Oṣu Kini, ọdun 2022.

Àjo ìgbàmọ̀ràn Árewá  (ACF) ti gbóríyìn fún Olóògbé Olúbàdàn, Sálìù Adétúnjí sàpéjúwe rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí olórí ìtèsíwájú ìbílẹ̀, tó mú ìtèsìwájú àti ìdúróṣinṣin bá ìlú Ìbàdàn

Ọ gbadura pe ki Ọlọrun fun wọn lọgbọn ati oye lati yan ẹni to yẹ sipo Olubadan  ti o papo da.

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button