v
Aṣojú àriwá Kwara níbi Àpèjọ Karùn ùn Àwọn ọ̀dọ́ Nàìjíríà, Ibraheem Abdullateef, képe àwọn ẹgbẹ́ òsèlú pàtàkì láti dín owó fọ́mùù yíyan olùdíje kù ṣaájú ìdìbò 2023, láti fààyè gba ìjọba tiwantiwa àti kíkópa.
Ijabọ naa wa ninu atẹjade kan ti awọn ọdọ fọwọ si ni ọjọ aiku, ti akọle rẹ jẹ ‘2023: APC, PDP, ati awọn miiran yẹ ki o din owo fọọmu idije ku fun awọn ọdọ pẹlu ida ọgọta.
Gẹgẹ bi o ti sọ, Fọọmu naa lọ fun ogun miliọnu. Awọn ẹka mejeeji si jẹ miliọnu kan si ogun miliọnu ni sisẹntẹle.
Gege bi o ti sọ, o yẹ ki ẹdinwo naa wa fun awọn oludije ti o wa labẹ ọdun karunle-lọgbọn.
Leave a Reply