Take a fresh look at your lifestyle.

COVID-19: Awọn Eniyan Ojì le ni ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ́wá (1940) Miiran Tun Ti Ni Aarun Corona Ni Ilu Naijiria

0 433

Ojì le ni ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ́wá awon eniyan lo ti ko ajakalẹ̀ arun buruku ni, Covid-19 ni orilẹ̀ ede Naijiria.

Ajọ to n ri si iṣakoso arun ni orilẹ̀ ede Naijiria (NCDC) lo so eyi di mimọ ni owurọ ọjọ Jimọ nipasẹ oju-iwe Facebook rẹ

Ipinlẹ̀ mokandinlogun (19) ti wọn ti ni aarun naa ni; Eko- ẹ́ẹdógún-din-ni-ọ́ta le ni ẹgbẹ́rin (845), ỌYọ- ọgọfa (120), Riversọ̀kan din ni àádọ́rin (69), Delta- 30 ọgbọn (30), Kaduna- ọkandinlọgbọn (29), ẹdo– ọkanlelogun (21), Plateau- Ogun (20), Gombe- ẹrinla (14), Anambra- mọkanla (11), Enugumọkanla (11),  Osun- mẹẹwa (10), Ekiti- mẹẹjọ (8), Kano- maarun (5), Bayelsa- mẹẹrin (4), Ogun- mẹẹrin (4), Katsina- mẹẹta (3), Bauchi- ọkan (1), Jigawa- ọkan (1)

 

 

Akinseye Tolulope

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button