Take a fresh look at your lifestyle.

APC Bẹ̀rẹ̀ Ìgbáradì Fún Àpéjọ Orílẹ̀-èdè

0 245

Ní ìgbáradì fún àpèjọ orílẹ̀-èdè rẹ̀, ẹgbẹ́ alákoso Nàìjíríà, APC, ti pinnu láti ṣètò àwọn ìgbìmọ̀ kékeré lórí ìsúná àti àwọn ẹ̀ka pàtàkì mííràn.

Akọ̀wé aṣojú ẹgbẹ́ APC lórílẹ̀-èdè náà, Sẹnetọ John Akpanudoedehe ló sọ èyí nígbà tó ń sọ̀rọ̀ fáwọn akọ̀ròyìn lẹ́yìn ìpàdé ìgbìmọ̀ tó ń bójú tó àpéjọpọ̀ àpéjọ àgbáyé ní ìlú Abuja. Senato Akpanudoedehe sọ pe ipade naa ṣe agbeyewo awọn idawọle ẹgbẹ naa lati bi ọdun kan sẹyin

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button