Take a fresh look at your lifestyle.

Ààrẹ gba abẹ́rẹ́ àjẹsára tó tún lágbára jù

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

0 413

Ààrẹ Mùhámmádù Bùhárí ti gba abẹ́rẹ́ àjẹsára còrónà, ní èyí  tó jẹ́ agbátẹrù rẹ̀.

Dọkita rẹ, Dokita Suhayb Rafndadi, ni o fun ni abẹrẹ ajẹsara naa ni ọjọ iṣẹgun,ni deede agogo mẹsan aabọ , ni Villa ,ile-iṣẹ aarẹ, Abuja.

Akowe Alaṣẹ Ile-iṣẹ Idagbasoke Itọju Ilera Alakọbẹrẹ (NPHCDA), Dokita Faisal Shuaib, ba Awọn oniroyin villa sọrọ ni kete  ti aarẹ gba ajẹsara rẹ. O sọ pe aarẹ tun ti ṣe afihan adari pẹlu apẹẹrẹ nipa  igbelaruge gbigba ajẹsara naa.

Shuaib mu da  awọn  ara ilu  loju pe,abẹrẹ ajesara  corona ko lewu; bayi,ki  wọn  tu yahayaha ,ki gbogbo eniyan lọ gbaa fun idaabobo ara wọn.

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button