Take a fresh look at your lifestyle.

Ààrẹ ń darí àpèjọ lórí ayélujára

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

0 247

Ààrẹ Mùhámmádù Bùhárí ń darí àpèjọ ìgbìmọ̀ aláṣẹ àpapọ̀ ọlọ́sọ̀ọ̀sẹ̀ lọ́wọ́lọ́wọ́ ní ilé-ìgbìmọ̀.

Igbakeji Aarẹ Yẹmi Ọsinbajo, Akowe fun ijọba apapọ, Boss Mustapha ati ọga agba oṣiṣẹ fun Aarẹ, Ọjọgbọn Ibrahim Gambari ati Olori awọn oṣiṣẹ ijoba lapapọ, Folashade Yẹmi-Ẹsan wa lara awon ti wọn  peju sibi ipade naa,eyi ti o bẹrẹ ni deede agogo mẹsan owurọ.

Awọn minisita ti o tun wa nibẹ ni  Alaye ati Aṣa, Lai Mohammed, Isuna, Inawo ati  Eto Orilẹ-ede, Zainab Ahmed, Ofurufu, Hadi Sirika, ati ibaraẹnisọrọ ati ọrọ- Aje ori ayelijara, Isa Pantami.

Awọn yooku ni  minisita ti ọrọ ọlọpa, Maigari Dingyadi, Agbara, Abubakar Aliyu ati ti Iṣẹ ati Ibugbe, Babatunde Fashọla.

Awọn minisita miiran n kopa lati awọn ọfiisi  wọn lọlọkanọjọkan ni Abuja.

Alaye nigba miran…

 

 

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button