Take a fresh look at your lifestyle.

Ẹ mẹ́nu kúrò níbi ìbàjẹ́

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

0 236

Iléeṣẹ́ Ààrẹ ti fesi sí àtẹ̀jáde kan tí ìwé ìròyìn kan ní Nàìjíríà fọwọ́ sí, èyí tó sọ pé ìjọba òde òní kò ṣe ohun tó tó láti yanjú àwọn ìṣòro ààbò tó ń dojú kọ àwọn àgbègbè kan lórílẹ̀-èdè náà.

Ninu ifiranṣẹ kan ti o fi sita ni alẹ ọjọ Aiku, Oluranlọwọ pataki si aarẹ lori eto iroyin ati ikede, Garba Shehu, sọ pe; “Ni pataki lori ọrọ ti Daily Trust fi sita loni, Ọfiisi ti Aare yoo fesi le.

Osọ pe ,ọrọ asọdun lasun leleyii,ko ri bẹẹ rara.

O wa  ń gba ìwé ìròyìn náà níyànjú pé kí wọ́n jáwọ́ nínú ìròyìn onímọtara-ẹni-nìkan, olùrànlọ́wọ́ Ààrẹ fi dá orílẹ̀-èdè  lójú pé, àwọn ìgbésẹ̀ tí ìjọba ń gbé yóò mú èso rere jade,nigbati ó bá fẹ́ jáde.

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button