Take a fresh look at your lifestyle.

Ènìyàn ààdọ́fà míràn tún ti kó ààrùn corona

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

0 288

Àwọn ènìyàn ààdọ́fà míràn tún ti kó ààrùn covid ní orílẹ̀-èdè.

Ile-iṣẹ to n mojuto ajakalẹ aarun lorile-ede NCDC sọ eleyi di mimọ lori wẹẹbu wọn.

Gẹgẹ bii ile-iṣẹ ọhun,NCDC sọ pe awọn eniyan aadọfa ọhun jẹyọ lati ipinlẹ mejila- Lagos (mẹtedin-lọgbọn), Katsina (mẹtale-logun), Rivers (ogun), Ondo (mọkanla), Kaduna (mẹsan), Olu-ilu (mẹfa), Oyo (mẹfa), Plateau (mẹta), Osun (meji), Ekiti (ẹyọkan), Gombe (ẹyọkan),  Zamfara (ẹyọkan).

Lọwọlọwọ bayii,eniyan ẹgbàájì le ni ọ̀kẹ́ mẹ̀wá abo o le ni èjì le ni àádọ́rùn lo ti ko aarun corona, ẹ̀ẹ́dẹ́gbàrin- le- ni- ọ̀kẹ́- mẹ̀wá- o- le –ni- eérinlá- le- ni- ojì-le-nigba eniyan ti gba iwosan,ti eniyan ẹ̀rin-le-ni-okòó- din-  lẹgbẹ́ẹ́ẹdógún si ti jẹpe oluwa.

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button