Take a fresh look at your lifestyle.

Adarí Àjọ nimasa gba àmì ẹ̀yẹ ZIk

0 382

Àjọ tó ń mójútó ètò  omi lorilẹ ede Naijiria (NIMASA), Bashir Jamoh, ti gba  àmì ẹ̀yẹ Zik fun isẹ takun-takun ti o  ti gbe se lorilẹ ede Naijria fun ọdun 2020.

Ajọ to n mojuto eto iwadii ati atuapalẹ isẹ ọhun, wa kán saara si Jamoh fun gudugudu-meje-yaya-mẹfa ti o gbe ṣe ni ajọ NIMASA nipa awon orisirisi iṣẹ ribiribi ti o gbe ṣe, eyi ti o ti mu idagbasoke ati ilosiwaju ba NIMASA ni won ṣe daa lola.

Awon Aṣoju lati ọdọ  gomina ipinlẹ Kaduna, Nasir El-Rufai,  adari ile igbimọ aṣofin ipinlẹ Kaduna, awọn ọba, ati awọn adari  ijọba ipinlẹ Kaduna miran wa lati ṣe atilẹyin fun Ọjọgbọn Jamoh.

 

 

 

 

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button