Take a fresh look at your lifestyle.

Ayẹyẹ EndSARS : Àwọn ikọ̀ ọmọ ogun kò yìnbọn pa àwọn a-fẹ̀hònúhàn ní ibùdó ọkọ̀ Lekki – Lai

Ademola Adepoju

0 434

Ijọba orilẹ ede Naijiria ti tun tẹnumọ ọn pe , ikọ ọmọ ogun orile ede Naijiria ti wọn ko lọ lati pese aabo ni ipinlẹ Eko, paapaa julọ ni ibudo ọkọ Lekki ko yinbọn pa ẹnikankan ninu awọn to fẹhonuhan lati gbogun t bi awọn ọlọpaa SARS se n hu  iwa ibajẹ ati sise awọn eniyan ni ijamba, ni eyi to waye ni ogunjọ osu kẹwaa ọdun, 2020.

Minisita fun iroyin ati asa lorilẹ ede Naijiria , Lai Mohammed lo sọrọ yii niluu Abuja lọjọRu pẹlu awọn akọroyin.

Mohammed  tun bẹnu àtẹ lu bi awọn ile-isẹ iroyin  Cable News Network, CNN fun bi wọn ko ,lati jẹrisi ẹsun ipaniyan  ti wọn sọ pe o sẹlẹ ni se yọju si  Igbimọ to n se  Iwadii nipa iwa ipaniyan to waye ni ibudo ọkọ̀ Le rẹ ni Lekki .

Lai tun tẹsiwaju pe “Àwọn ipinlẹ mọkanla lo ti pari isẹ́ wọn lori abajade ohun ti igbimọ to n se itọpinpin lori isẹlẹ ọhun se,  , awọn ipinlẹ naa ni(Abia, Ekiti, Enugu, Gombe, Kwara, Nasarawa, Ogun, Ondo, Osun, Plateau, ati Rivers) Awọn gomina yooku ni awọn ko ni pẹ gbe abajde tiwọn naa wa.”

Ohun ti igbimọ ijọba fẹnuko le lori ni pe awọn awọnnyoo san owó gba maa-binu fun awọn to farapa yala awọn osisẹ agbofinro tabi awọn eniyan.

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button