Take a fresh look at your lifestyle.

Ààrẹ Bùhárí gba ààrẹ orílẹ̀-èdè Turkey lálejò ní ìlú-Àbújá

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

0 345

Ààrẹ  Reccep Tayyip Erdogan orílẹ̀-èdè Turkey ti gúnlẹ̀ sí gbọ̀ngàn ààrẹ  ní Víllà, Àbújá fún àbẹ̀wò ọlọ́jọ́ méjì.

Aarẹ gbalejo Erdogan,ẹni ti o gunlẹ si olu-ilu Naijiria ni deede agogo mẹwa kọja iṣẹju meje owurọ.

Lẹsẹkẹsẹ ti o gunlẹ ni wọn ti wọle lọ ṣe apejọ bonkẹlẹ, nibiti wọn yoo ti  ṣapero  lori awọn  adehun to ju ogun lọ ati awọn iwe adehun , eyiti  orilẹ -ede mejeeji yoo fọwọ si nigbamii.

Aarẹ Buhari yoo gba alejo rẹ lẹyin ounjẹ ọsan, lẹyin eyi, wọn yoo jọ ba awọn oniroyin Ile Ijọba sọrọ papọ.

Awọn alaye nigbamii.

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button