Take a fresh look at your lifestyle.

Ìdáàbòbò Àwọn amáyédẹrùn Pàtàkì ṣe pàtàkì fún Ààbò lórí ìmọ̀ ayélujára -–Mínísítà

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

0 372

Mínísítà fún ètò Ìbáraẹnisọ̀rọ̀ àti ọrọ̀ Ajé orí ayélujára , Ọ̀jọ̀gbọ́n Isa Pantami sọ pé, àyàfi tí wọ́n  bá gbé àwọn ìgbésẹ̀ àdáṣe láti dáábòbò àwọn amáyédẹrùn pàtàkì àti àwọn ohun -ìní Nàìjíríà,tí kò bá jẹ́ bẹ́ẹ̀,èyí  le fa  àwọn ìkọlù orí ayélujára tó burú jàì.

Dokita Pantami ṣalaye eyi ni Apejọ kan ti awọn alabaṣepọ lori Idaabobo  Awọn amayedẹrun Pataki ti ile iṣẹ Aabo ati idaabobo ara ilu  (NSCDC) ṣagbekalẹ rẹ,ti akọle rẹ jẹ, ‘ajọṣepọ: igbesẹ to tọ si Awọn Ohun -ini Pataki Ti o munadoko ati Idaabobo Amayedẹrun,’ ni ilu Abuja.

O sọ pe,ile- iṣẹ  rẹ n ṣiṣẹ lori aṣẹ  lati pese aabo to peye  fun awọn amayedẹrun ni orilẹ -ede.

O  gbero fun itaniji  awọn ara ilu ati ọna iṣatunṣe lati  kan  awọn ara ilu nipa lori didaabobo awọn ohun-ini orilẹ-ede laarin ara wọn.

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button