Take a fresh look at your lifestyle.

gbígbógun ti òògùn olóró: Nàìjíríà, Saudi Arabia ṣerawọn lóṣùṣù ọwọ̀

Eyitayọ Fauziay Oyetunji

0 361

Ilé -iṣẹ́ tó ń ṣòfin lórí òògùn olóró ní Orílẹ̀ -èdè Nàìjíríà, NDLEA àti Olùdarí ẹka to n gbogun ti oogun oloro lorilẹ ede  Saudi Arabia (GDNC), ti gbà láti tùbọ̀ fìdí àjọṣepọ̀ wọn múlẹ̀ lórí gbígbógun ti gbígbé  àti mimu òògùn olóró   láàrin àwọn orílẹ̀ -èdè méjèèjì.

Eyi ni koko  ijiroro  ti NDLEA, ajagunfẹyinti  Mohammed Buba Marwa  ati aṣoju Saudi GDNC,  Naser Hajid Al Otaibi, jọ se  niluu Abuja,lorilẹ ede  Naijiria.

Lakooko to n  itẹwọgba awọn aṣoju Saudi, ajagunfẹyinti Marwa fi imoore rẹ han fun atilẹyin lati ọdọ ijọba Saudi latẹyinwa.

Oludari NDLEA bẹbẹ fun iranlọwọ lati  ọdọ ijọba orilẹ ede  Saudi fun atilẹyin wọn .

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button