Take a fresh look at your lifestyle.

ìjà ogun TIGRAY: Adarí ìgbìmọ̀ ìjọba orílẹ̀ èdè Ethiopia bẹ̀bẹ̀ fún ìrànwọ́ àwọn ará ìlú

Ademọla Adepọju

58

Adarí ìgbìmọ̀ ìjọba orílẹ̀ èdè Ethiopia Abiy Ahmed  ti rawọ ẹ̀bè si  gbogbo àwọn  ọmọ orílẹ̀-èdè Ethiopia láti darapọ̀ mọ́  ikọ̀ àwọn ọmọ ogun  orilẹ ede naa láti kọjú ogun ti ikọ̀ àwọn ọlọ̀tè ní àwọn agbègbè ẹkùn  Tigray nítorí pé, Ìjà náà ti pọ̀ si láti Osù keje nígbà tí àwọn  ikọ̀ ọlọ̀tè àti àwọn alájọṣepọ̀ wọn ti fẹ gba ẹkun  Tigray (TPLF) mọ́ wọn lọ́wọ́ .

Ìjà yii bẹ̀rẹ̀ léyìn ìgbà tí àwọn ọmọ ogun ijọba àpapọ̀  fi isẹ́ sílẹ̀ tí wọ́n sì se ìkéde  lati fopin is ogun pipa ara wọn.

Ni ọsẹ to kọja,  olori ikọ̀  awọn ọlọte naa  sọ pe ikọlu  naa waye lati gbogun ti didena ikọ ọmọ ogun ti ijọba lati ri eto iranwọ gba lati ọdọ awọn ẹkun ati agbaegbe to n seto iranwọ fun wọn.

 

Amọsa, adari igbimọ ijọba ti fẹsun kan ikọ awọn ọlọtẹ bi wọn se n dena to iranwọ ati lati maa jẹ ki awọn agbẹ raye lati gbin awọn nnkan ogbin wọn.

 

 

Hamzat Damola

Leave A Reply

Your email address will not be published.