Take a fresh look at your lifestyle.

U-20 AFCON: CAF Kọ́ Ẹyìn Sí Pápá Ìṣéré Alexandria Fún Àwọn Ìfẹsẹwọnsẹ́ Tó Kù

0 508

Àjọ àgbábọ́ọ̀lù Ilẹ̀ Áfíríkà (Confederation of African Football CAF) tí gbé pápá ìṣéré Alexandria jù sílẹ̀ látí gbàlèjò àwọn ìdíje tí ń lọ́ lọ́wọ́ níbí ìdíje Adúláwọ̀ tí ọjọ́ orí wọ́n ó jù ogún ọdún lọ́, 2023 ní atẹle ẹdun ọkàn àwọn ẹgbẹ́ kàn ní ìsọ̀rí C.

Ẹgbẹ́ àgbábọ́ọ̀lù náà kéde ìpinnu lẹyìn tí àwọn ẹgbẹ́ nínú ẹgbẹ́ náà nípa pápá ìṣéré náà.

Tún kà nípa:U-23 AFCON: Nàìjíríà Gbo Ewúro Sí Ojú Tanzania Ní Ayò 2-0

Ìgbìmọ̀ élétó tí pinnu láti gbé àwọn eré tó kù látí pápá iṣere Alexandria sí pápá iṣere Haras El Hodoud, tó wà nítòsí, ní Alexandria náà.” CAF sọ.

Pápá iṣere Haras El Hodoud yóò gbàlèjò àwọn eré fún ọjọ́ Kejì ní ìsọ̀rí C, ní ọjọ́ Ẹtì yìí, láàrín Benin atí Tunisia àti láàrín Gambia pẹ̀lú Zambia

Lekan Orenuga

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button