Ààrùn ibà Dengue ń gbilẹ̀ ní Sokoto, tí ẹ̀mí kan sì lọ síi
Ilé iṣé tí ń rí sí ìmójútó àti ìdènà àjàkálẹ̀ Ààrùn ní Nàìjíríà (NCDC), ti jábọ̀ pé wọ́n ti fura sí ènìyàn mọ́kàndín-lógún tó ní ààrun ibà dengue nínu oṣù kọkànlá 2025, pẹ̀lú àwọn mẹ́f̀a tí…