Take a fresh look at your lifestyle.
Browsing Tag

TETFUND

TETFUND Gbóríyìn Fún Ètò-Ẹkọ Àti Ètò Ìdàgbàsókè Tí Gómìnà Ìpínlẹ̀ Kwara

‎ Ọkàn nínú àwọn Ọmọ ẹgbẹ́ ìnáwó ètò ẹ̀kọ́ ilé-ẹ̀kọ́ gíga (Tertiary Education Trust Fund TETFUND) tó ń sójú agbègbè àárín gbùngbùn àríwá, Engineer Nurudeen Adeyemi Balogun ṣé àbẹwò sí Gómìnà Ìpínlẹ̀ Kwara tó tún jẹ́ Alága Ìgbimọ àwọn Gómìnà…

Ààrẹ Buhari Ṣí Àwọn Ìṣẹ́ Àkànṣe TETFUND Ẹlẹgbẹ-gbẹ́ Bílíọ̀nù Náírà Ní Makurdi

Ààrẹ Muhammadu Buhari ní Ọjọ́bọ̀, tí ṣí àwọn iṣẹ́ àkànṣe mẹ́fà nípasẹ̀ Àjọ ìnáwó Ilé-ẹ̀kọ́ gíga (Tertiary Education Trust Fund TETFUND) ní ilé-ìwé gíga tí Benue State University, Makurdi, ní Àárín gbùngbùn Àríwá, Nàìjíríà. Ààrẹ Buhari…
button