Kefas Agbu Ọmọ Ẹgbẹ́ PDP Bórí Ìdìbò Gómìnà Ìpínlẹ̀ Taraba
Àjọ élétó ìdìbò orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, INEC tí kéde Kefas Agbu tí ọmọ ẹgbẹ́ (Peoples Democratic Party), PDP gẹ́gẹ́ bí Gómìnà tó bórí ìbò ní ìpínlẹ̀ Taraba lẹyìn tó gbà ìbò tó pọ̀ jùlọ nínú ìdìbò Gómìnà tó wáyé lọ́jọ́ kejidinlogun, oṣù kẹta.…